Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni kí o fi ìrísí i wa wé ti àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin tí wọ́n ń jẹ oúnjẹ ọba, kí o sì ṣe àwa ìránṣẹ́ rẹ ní ìbámu pẹ̀lú u bí o bá ṣe rí i sí.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 1

Wo Dáníẹ́lì 1:13 ni o tọ