Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n olórí àwọn ìwẹ̀fà sọ fún Dáníẹ́lì pé, “Mo bẹ̀rù Olúwa mi, ẹni tí o ti pèṣè oúnjẹ àti ohun mímu rẹ. Báwo ni ìrísí ì rẹ yóò ṣe burú jù ti àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin ẹlẹgbẹ́ ẹ̀ rẹ lọ? Nígbà náà ni èmi yóò fi orí mi wéwu lọ́dọ̀ ọba.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 1

Wo Dáníẹ́lì 1:10 ni o tọ