Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ẹ ń wí pé,“Nígbà wo ni oṣù tuntun yóò paríkí àwa bá à lè ta ọkàkí ọjọ́ ìsinmi kí ó lè dópinkí àwa bá à le ta jéró?”Kí a sì dín ìwọ̀n wa kùkí a gbéraga lórí iye tí a ó tà ákí a sì fi òṣùnwọ̀n èké yàn wọ́n jẹ

Ka pipe ipin Ámósì 8

Wo Ámósì 8:5 ni o tọ