Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 7:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí náà, èyí ni ohun ti Olúwa wí:“ ‘Ìyàwó rẹ yóò di paṣángà ni ìlú,àwọn ọmọ ọkùnrin àti obìnrin rẹ yóò ti ipa idà ṣubú.A ó wọn ilẹ̀ rẹ, a ó sì pín inàti ìwọ pẹ̀lú yóò kú ni ilẹ̀ àìmọ́.Ísírẹ́lì yóò sì lọ sí ìgbèkùn,kúrò ní ilẹ̀ ìní wọn.’ ”

Ka pipe ipin Ámósì 7

Wo Ámósì 7:17 ni o tọ