Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 7:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Olúwa mu mi bí mo ti ń tọ́ agbo ẹran lẹ́yìn, ó sì wí fun mi pé, ‘Lọ sọtẹ́tẹ̀ fun àwọn Ísírẹ́lì ènìyàn mi.’

Ka pipe ipin Ámósì 7

Wo Ámósì 7:15 ni o tọ