Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 6:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa ọ̀gá ògo ti búra fúnra rẹ̀ Olúwa Ọlọ́run alágbára sì ti wí pé:“Mo kórìíra ìgbéraga Jákọ́bùn kò sì ní inú dídùn sí odi alágbára rẹ̀Èmi yóò sì fa ìlú náà lé wọn lọ́wọ́àti ohun gbogbo tí ó wà nínú rẹ̀.”

Ka pipe ipin Ámósì 6

Wo Ámósì 6:8 ni o tọ