Ẹ̀yin sùn lé ibusùn tí a fi eyín erin ṣeẸ sì tan ara sílẹ̀ ni orí àwọn ibùsùnẸ̀yin pa èyí tí o dára nínú àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn yín jẹẸ sì ń pa àwọn ọ̀dọ́ màlúù láàrin agbo wọn jẹ