Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ ẹṣin a máa sáré lórí àpáta bí?Ǹjẹ́ ènìyàn a máa fi ẹṣin kọ́ ni lórí àpáta bí?Ṣùgbọ́n ẹ̀yin ti yí ọ̀títọ́ padà sí májèléẸ sì ti sọ èso òdodo di ìkorò.

Ka pipe ipin Ámósì 6

Wo Ámósì 6:12 ni o tọ