Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹbí tí ó yẹ kí ó gbé òkú wọn jáde fún sínsin bá wọlé, bí o ba sì béérè pé ǹjẹ́ ẹnìkan wa tí ó farapamọ́ níbẹ̀, “Njẹ ẹnìkankan wà lọ́dọ̀ yín?” tí ó bá sì dáhùn wí pé, “Rárá,” nígbà náà ni yóò wí pé, “Pa ẹnu rẹ mọ́ àwa kò gbọdọ̀ dárúkọ Olúwa.”

Ka pipe ipin Ámósì 6

Wo Ámósì 6:10 ni o tọ