Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 5:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò dàbí ọkùnrin tí ó sá láti ẹnu àmọ̀tẹ́kùn.Tí ó padà wá bọ́ sí ẹnu ẹkùnyóò dàbí ẹni tí ó wọ ilé rẹ̀ lọtí ó simi lé ògiri ilé rẹ̀tí ejò sì bù ú ṣán.

Ka pipe ipin Ámósì 5

Wo Ámósì 5:19 ni o tọ