Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 5:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa, Ọlọ́run alágbára wí:“Ẹkún yóò wà ní àwọn òpópónàigbe ìnira yóò sì wà ní àwọn gbàgede ìlúA ó kó àwọn àgbẹ̀ jọ láti sunkúnÀti àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀ láti pohùnréré ẹkún

Ka pipe ipin Ámósì 5

Wo Ámósì 5:16 ni o tọ