Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 5:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ń tẹ talákà mọ́lẹ̀o ń fi ipá gba ọkà lọ́wọ́ wọnNítorí náà, ìwọ ti fi òkúta tí a gbẹ́ kọ́léṣùgbọ́n ẹ kò sì ní gbé inú wọnNítòótọ́ ìwọ ti gbin ọgbà àjàrà tí ó lẹ́wà.Ìwọ kò ní mu wáìnì inú wọn

Ka pipe ipin Ámósì 5

Wo Ámósì 5:11 ni o tọ