Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ́pọ̀ ìgbà ni mo lu ọgbà àti ọgbà àjàrà yínmo fi àrá àti ìrì lù wọ́n.Esú sì jẹ igi ọ̀pọ̀tọ́ àti igi ólífì yín,ṣíbẹ̀ ẹ̀yin kò yípadà sí mi,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Ámósì 4

Wo Ámósì 4:9 ni o tọ