Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo rán àjàkálẹ̀-àrùn sí i yínbí mo ti ṣe sí Éjíbítì.Mo fi idà pa àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin yín.Pẹ̀lú àwọn ẹṣin tí a kó ní ìgbékùn.Mo kún imú yín fún òórùn ibùdó yín,síbẹ̀ ẹ̀yin kò yípadà sí mi,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Ámósì 4

Wo Ámósì 4:10 ni o tọ