Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 3:2-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. “Ìwọ nìkan ni ẹni tí mo yànnínú gbogbo àwọn ìran ayé yìí;nígbà náà èmi ó jẹ ọ́ níyàfún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.”

3. Ẹni méjì ha à le rìn pọ̀láìjẹ́ pé wọ́n ti gbà láti ṣe é?

4. Ǹjẹ́ Kìnnìún yóò ha bú ramúramù nínú igbo,bí kò bá ní ohun ọdẹ?Ọmọ kìnnìún yóò ha ké jáde nínú ìhó rẹ̀bí kò bá rí ohun kan mú?

Ka pipe ipin Ámósì 3