Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 3:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run ti sọ nípa rẹ̀, ẹ̀yin ènìyàn Ísírẹ́lì nípa àwọn ìdílé tí mo mú jáde láti Éjíbítì:

2. “Ìwọ nìkan ni ẹni tí mo yànnínú gbogbo àwọn ìran ayé yìí;nígbà náà èmi ó jẹ ọ́ níyàfún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.”

3. Ẹni méjì ha à le rìn pọ̀láìjẹ́ pé wọ́n ti gbà láti ṣe é?

Ka pipe ipin Ámósì 3