Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa wí:“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta ti Júdà,àní fún mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padàNítorí wọn ti kọ òfin Olúwa sílẹ̀wọn kò sì pa àwọn ìlànà rẹ̀ mọ́Nítorí àwọn òrìṣà ti sì wọ́n lọ́nàÒrìṣà tí àwọn Baba ńlá wọn ń tẹ̀lé

Ka pipe ipin Ámósì 2

Wo Ámósì 2:4 ni o tọ