Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 2:13-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. “Ní báyìí, èmi yóò tẹ̀ yín mọ́lẹ̀bí kẹ̀kẹ́ tí ó kún fún ìtí ti í tẹ̀.

14. Ẹni tí ó yára bí àṣá kò ní rí ọ̀nà àbáyọalágbára kò ní le è dúró lé agbára rẹ̀jagunjagun kì yóò le gba ẹ̀mí ara rẹ̀ là

15. tafàtafà kì yóò dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ̀bẹ́ẹ̀ ni ẹni tí ó gún ẹṣinkì yóò gba ẹ̀mí ara rẹ̀ là

16. àní jagunjagun tí ó gbóyà jùlọyóò sálọ ní ìhòòhò ní ọjọ́ náà,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Ámósì 2