Èmi sì tún gbé àwọn wòlíì dìde láàárin àwọn ọmọ yínàti láàárin àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin yín láti jẹ Násárátìèyí kò ha jẹ́ òtítọ́ bí ará Ísírẹ́lì?”ni Olúwa wí.