Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 2:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èyí ni ohun tí Olúwa wí;“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta ti Móábù,àní fún mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padà,Nítorí ó ti sun-ún, di eérú,egungun ọba Édómù

2. Èmi yóò rán iná sí orí MóábùÈyí tí yóò jó àwọn ààfin Kéríótì run.Móábù yóò sì kú pẹ̀lú ariwopẹ̀lú igbe àti pẹ̀lú ìró ìpè

Ka pipe ipin Ámósì 2