Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò ṣẹ́ ọ̀pá ìdáàbú Dámásíkù;Èmi yóò sì pa ọba tí ó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Áfénì runÀti ẹni tí ó di ọ̀pá aládé mú ní Bẹti-Édénì.Àwọn ará a Árámù yóò lọ sí ìgbèkùn sí Kírì,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Ámósì 1

Wo Ámósì 1:5 ni o tọ