Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa wí:“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta tí Dámásíkù,àní fún mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padaNítorí wọn fi ohun èlò ìpakà pa Gílíádì.Pẹ̀lú ohun èlo irin tí ó ní eyín mímú

Ka pipe ipin Ámósì 1

Wo Ámósì 1:3 ni o tọ