Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti ìgbòòrò Ìjọba rẹ̀ àti àlàáfíà rẹ̀ ni kì yóò ní ìpẹ̀kun.Yóò jọba lórí ìtẹ́ Dáfídìàti lórí ẹ̀kún un rẹ̀ gbogbo,nípa ìfìdímúlẹ̀ àti ìgbéró rẹ̀,pẹ̀lú òtítọ́ àti òdodoláti ìgbà náà lọ àti títí láéláé.Ìtara Olúwa àwọn ọmọ-ogunni yóò mú èyi ṣẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 9

Wo Àìsáyà 9:7 ni o tọ