Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 9:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mánásè yóò máa jẹ Éfáímù, nígbà tí Éfáímù yóò jẹ Mánásèwọn yóò parapọ̀ dojúkọ Júdà.Ṣíbẹ̀síbẹ̀, ìbínú un rẹ̀ kò yí kúròỌwọ́ọ rẹ̀ sì wà ní gbígbéró.

Ka pipe ipin Àìsáyà 9

Wo Àìsáyà 9:21 ni o tọ