Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 9:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní apá ọ̀tún wọn yóò jẹrun,síbẹ̀ ebi yóò sì máa pa wọ́n,ní apá òsì, wọn yóò jẹṣùgbọ́n, kò ní tẹ́wọn lọ́rùn.Ẹnìkọ̀ọ̀kan yóò sì máa jẹ ẹran-ara ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 9

Wo Àìsáyà 9:20 ni o tọ