Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 66:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ìdí èyí ni èmi pẹ̀lú yóò ṣe fi ọwọ́ líle mú wọnn ó sì mú ohun tí wọ́n bẹ̀rù rẹ̀ wá sórí wọn.Nítorí nígbà tí mo pè, kò sí ẹni tí ó dáhùn,nígbà tí mo sọ̀rọ̀, ẹnikẹ́ni kò tẹ́tísílẹ̀.Wọ́n ṣe ohun búburú ní ojú miwọ́n sì yan ohun tí mo kóríìra rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 66

Wo Àìsáyà 66:4 ni o tọ