Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 66:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ẹni tí ó fi akọ màlúù rúbọó dàbí ẹni tí ó pa ènìyàn kanàti ẹni tí ó bá fi ọ̀dọ́ àgùntàn kan tọrẹ,dàbí ẹni tí ó kán ajá kan lọ́rùn;ẹnikẹ́ni tí ó bá fi irúgbin oníhóró tọrẹdàbí ẹni tí ó mú ẹ̀jẹ̀ ẹlẹ́dẹ̀ wá,ẹni tí ó bá sì ṣun tùràrí ìrántí,dàbí ẹni tí ó sin ère òrìṣà.Wọ́n ti yan ipa ọ̀nà tiwọn,ọkàn wọn pẹ̀lú sì láyọ̀ nínú ohun ìríra wọn;

Ka pipe ipin Àìsáyà 66

Wo Àìsáyà 66:3 ni o tọ