Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 65:23-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

23. Wọn kì yóò ṣe wàhálà lásántàbí kí wọn bímọ tí ọjọ́ iwájú wọnkì yóò sunwọ̀n;nítorí wọn yóò jẹ́ àwọn ènìyàn ti Olúwa bùkún fún,àwọn àti àwọn ìrandíran wọn pẹ̀lú wọn.

24. Kí wọn tó pè, èmi yóò dáhùn;nígbà tí wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, èmi yóò gbọ́.

25. Ìkookò àti ọ̀dọ́ àgùntàn yóò jẹun pọ̀,kìnìún yóò sì jẹ koríko gẹ́gẹ́ bí akọ màlúù,ṣùgbọ́n erùpẹ̀ ni yóò jẹ́ oúnjẹ ejò.Wọn kì yóò panilára tàbí panirunní gbogbo òkè mímọ́ mi,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 65