Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 65:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìkookò àti ọ̀dọ́ àgùntàn yóò jẹun pọ̀,kìnìún yóò sì jẹ koríko gẹ́gẹ́ bí akọ màlúù,ṣùgbọ́n erùpẹ̀ ni yóò jẹ́ oúnjẹ ejò.Wọn kì yóò panilára tàbí panirunní gbogbo òkè mímọ́ mi,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 65

Wo Àìsáyà 65:25 ni o tọ