Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 65:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Èmi fi ara mi hàn fún àwọn tí kò béèrè fún mi;Àwọn tí kò wá mi ni wọ́n rí mi.Sí àwọn orílẹ̀ èdè tí kò pe orúkọ mi,Ni èmi wí pé, ‘Èmi nìyìí, Èmi nìyìí.’

2. Gbogbo ọjọ́ ni mo ti nawọ́ mi sítasí àwọn ènìyàn ọlọ́rùn líle,tí wọn ń rìn lọ́nà tí kò dára,tí wọ́n sì gbáralé èrò ara wọn

Ka pipe ipin Àìsáyà 65