“Èmi fi ara mi hàn fún àwọn tí kò béèrè fún mi;Àwọn tí kò wá mi ni wọ́n rí mi.Sí àwọn orílẹ̀ èdè tí kò pe orúkọ mi,Ni èmi wí pé, ‘Èmi nìyìí, Èmi nìyìí.’