Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 63:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú un gbogbo ìpọ́njúu wọn, inú òun pẹ̀lú bàjẹ́àti ańgẹ́lì tí ó wà níwájú rẹ̀ gbà wọ́n là.Nínú Ìfẹ́ àti àánú rẹ̀, ó rà wọ́n padà;ó gbé wọn ṣókè ó sì pọ̀n wọ́nní gbogbo ọjọ́ ìgbà n nì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 63

Wo Àìsáyà 63:9 ni o tọ