Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 63:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi nìkan ti dá tẹ ìfúntí wáìnì;láti àwọn orílẹ̀ èdè tí ẹnikẹ́ni kò sì wà pẹ̀lú mi.Mo tẹ̀wọ́n mọ́lẹ̀ ní ìbínú mimo sì tẹ̀ wọ́n rẹ́ ní ìrunú miẹ̀jẹ̀ wọn sì fọ́n sí aṣọ mi,mo sì da àbàwọ́n sí gbogbo aṣọ mi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 63

Wo Àìsáyà 63:3 ni o tọ