Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 63:17-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. Èéṣe Olúwa tí o fi jẹ́ kí a ṣáko kúrò ní ojú ọ̀nà rẹtí o sì ṣé àyà wa le tó bẹ́ẹ̀ tí àwa kò fi bọ̀wọ̀ fún ọ?Padà nítorí àwọn ìránṣẹ́ rẹ,àwọn ẹ̀yà tíi ṣe ogún ìní rẹ.

18. Fún ìgbà díẹ̀ ni àwọn ènìyàn rẹ fi gba ibi mímọ́ rẹ,ṣùgbọ́n nísinsìn yìí àwọn ọ̀tá wa ti tẹ ibi mímọ́ rẹ mọ́lẹ̀.

19. Àwa jẹ́ tìrẹ láti ìgbà n nì;ṣùgbọ́n ìwọ kò tí ì jọba lé wọn lórí,a kò sì tí ì pè wọ́n mọ́ orúkọ rẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 63