Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 63:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èéṣe Olúwa tí o fi jẹ́ kí a ṣáko kúrò ní ojú ọ̀nà rẹtí o sì ṣé àyà wa le tó bẹ́ẹ̀ tí àwa kò fi bọ̀wọ̀ fún ọ?Padà nítorí àwọn ìránṣẹ́ rẹ,àwọn ẹ̀yà tíi ṣe ogún ìní rẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 63

Wo Àìsáyà 63:17 ni o tọ