Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 61:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti láti pèṣè fún àwọn tí inú wọn bàjẹ́ ní Ṣíhónìláti dé wọn ládé ẹ̀yẹ dípò eérú,òróró ìdùnnú dípò ìbànújẹ́,àti aṣọ ìyìn dípò ìpòrúùru ọkàn.A ó sì pè wọ́n ní óákù òdodo,irúgbìn Olúwaláti fi ọláńlá rẹ̀ hàn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 61

Wo Àìsáyà 61:3 ni o tọ