Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 61:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gẹ́gẹ́ bí ilẹ̀ ti í mú èhù jádeàti bí ọgbà ṣe ń mú irúgbìn dàgbà,Bẹ́ẹ̀ ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò ṣe mú òdodo àti ìyìnkí ó ru sókè níwájú gbogbo orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin Àìsáyà 61

Wo Àìsáyà 61:11 ni o tọ