Àìsáyà 61:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Ẹ̀mí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wà lára minítorí Olúwa ti fi àmì-òróró yàn míláti wàásù ìhìnrere fún àwọn talákà.Ó ti rán mi láti ṣe àwòtan oníròbìnújẹ́láti kéde ìdásílẹ̀ fún àwọn ìgbèkùnàti ìtúsílẹ̀ kúrò nínú òkùnkùn fún àwọn ẹlẹ́wọ̀n,