Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 60:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ni gbogbo àwọn ènìyàn rẹ yóò di òdodoàwọn ni yóò sì jogún ilẹ̀ náà títí ayé.Àwọn ni èhù tí mo ti gbìn,iṣẹ́ ọwọ́ mi,láti fi ọlá ńlá mi hàn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 60

Wo Àìsáyà 60:21 ni o tọ