Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 60:20-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Òòrùn rẹ kì yóò sì wọ̀ mọ́,àti òṣùpá rẹ kì yóò sì wọ òòkùn mọ́; Olúwa ni yóò jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ayérayé rẹ,àti àwọn ọjọ́ arò rẹ yóò sì dópin.

21. Lẹ́yìn náà ni gbogbo àwọn ènìyàn rẹ yóò di òdodoàwọn ni yóò sì jogún ilẹ̀ náà títí ayé.Àwọn ni èhù tí mo ti gbìn,iṣẹ́ ọwọ́ mi,láti fi ọlá ńlá mi hàn.

22. Èyí tí ó kéré jù nínú un yín yóò di ẹgbẹ̀rún kan,èyí tí ó kéré yóò di orílẹ̀ èdè ńlá.Èmi ni Olúwa;ní àkókò rẹ̀ Èmi yóò ṣe èyí kánkán.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 60