Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 59:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àti fún èmi, májẹ̀mú mi pẹ̀lú wọn nìyìí,” ni Olúwa wí, “Ẹ̀mí mi, tí ó wà nínú yín, àti ọ̀rọ̀ mi tí mo ti fi sí ẹnu yín, kì yóò kúrò lẹ́nu yín, tàbí lẹ́nu àwọn ọmọ yín, tàbí láti ẹnu àwọn ìrandíran wọn láti àkókò yìí lọ àti títí láéláé” ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:21 ni o tọ