Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 59:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìwọ̀-oòrùn, àwọn ènìyàn yóò bẹ̀rù orúkọ Olúwa,àti láti ìlà oòrùn, wọn yóò bọ̀wọ̀ fún ògo rẹ̀.Nítorí òun yóò wá gẹ́gẹ́ bí i rírú omièyí tí èémí Olúwa ń tì lọ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:19 ni o tọ