Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 59:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo wa là ń ké bí i bíárì;àwa pohùnréré ẹkún bí àdàbàA ń wá ìdájọ́ òdodo ṣùgbọ́n kò sí; à ń wọ̀nàfún ìtúsílẹ̀, ṣùgbọ́n ó jìnnà réré.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:11 ni o tọ