Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 58:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti bí ẹ̀yin bá ná ara yín bí owó nítorí àwọn tí ebi ń patí ẹ sì tẹ́ ìfẹ́ àwọn tí à ń ni lára lọ́rùn,nígbà náà ni ìmọ́lẹ̀ yín yóò ràn nínú òkùnkùn,àti òru yín yóò dàbí ọ̀ṣán-gangan.

Ka pipe ipin Àìsáyà 58

Wo Àìsáyà 58:10 ni o tọ