Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 57:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ta ni ó ń pá yín láyà tí ń bà yín lẹ́rùtí ẹ fi ń ṣèké sí mi,àti tí ẹ̀yin kò fi rántí mitàbí kí ẹ rò yí nínú ọkàn yín?Ǹjẹ́ kì í ṣe nítoríi dídákẹ jẹ́ ẹ́ mi fún ìgbà pípẹ́tí ẹ̀yin kò fi bẹ̀rù mi?

Ka pipe ipin Àìsáyà 57

Wo Àìsáyà 57:11 ni o tọ