Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 57:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọ̀nà yín gbogbo ti mú àárẹ̀ baa yín,ṣùgbọ́n ẹ kò ní sọ pé, ‘kò sí ìrètí mọ́?’Ẹ rí okun kún agbára yín,nípá bẹ́ẹ̀ òòyì kò kọ́ọ yín.

Ka pipe ipin Àìsáyà 57

Wo Àìsáyà 57:10 ni o tọ