Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 56:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe jẹ́ kí àjèjì kan tí ó ti di ara rẹ̀mọ́ Olúwa sọ wí pé,“Olúwa yóò yà mí ṣọ́tọ̀ kúrò nínú àwọn ènìyàn rẹ̀.”Àti kí ìwẹ̀fà kí ìwẹ̀fà kan ṣe àròyé pé“Igi gbígbẹ lásán ni mí.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 56

Wo Àìsáyà 56:3 ni o tọ