Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 54:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Má ṣe bẹ̀rù, ìtìjú kò ní ṣubú lù ọ́.Má ṣe bẹ̀rù ìdójútì, a kì yóò kàn ọ́ lábùkù.Ìwọ yóò gbàgbé ìtìjú ìgbà èwee rẹÌwọ kì yóò sì rántí ẹ̀gàn ìwà-rópó rẹ mọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 54

Wo Àìsáyà 54:4 ni o tọ