Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 54:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a tilẹ̀ mi àwọn òkè ńlátí a sì sí àwọn òkè kékeré nídìí,Ṣíbẹ̀ ṣíbẹ̀ ìfẹ́ àìkùnà mi fún ọ kì yóò yẹ̀ láéláétàbí májẹ̀mú àlàáfíà ni a ó mú kúrò,”ni Olúwa, ẹni tí ó síjú àánú wò ọ́ wí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 54

Wo Àìsáyà 54:10 ni o tọ