Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 53:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A jẹ ẹ́ níyà, a sì pọ́n ọn lójú,ṣíbẹ̀ kò ya ẹnu rẹ̀;a mú un wá gẹ́gẹ́ bí ọ̀dọ́-àgùntàn sọ́dọ̀ alápatà,àti gẹ́gẹ́ bí àgùntàn tí ó dákẹ́ níwájú olùrẹ́run rẹ̀,ṣíbẹ̀ kò ya ẹnu rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 53

Wo Àìsáyà 53:7 ni o tọ